Bibeli sọtẹlẹ pe Ẹ̀mí ati Ìyàwó yoo fun lómi ìyè ní àkókò yìí (Ìfihàn 22:17).
Ẹ̀mí ni Ọlọ́run Baba.
Nigba naa, ta ni Ìyàwó ti o farahan pẹlu Ẹ̀mí ti o si fun wa lómi ìyè?
“Wá níhìn-ín, èmi ó fi ìyàwó,
aya Ọ̀dọ́-àgùntàn hàn ọ́.” . . .
ó sì fi ìlú náà hàn mi, Jerusalẹmu mímọ́,
tí ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá . . . (Ìfihàn 21:9–10)
Ṣùgbọ́n Jerusalẹmu ti òkè jẹ́ òmìnira,
èyí tí í ṣe ìyá wa. (Galatia 4:26)
Ni àwọn ọ̀rọ̀ míràn, níwọ̀n bí Ìyàwó ti Ẹ̀mí jẹ́ Ọlọ́run Ìyá,
a lè gba ìbùkún omi ìyè nígbà tí a bá gba
Ọlọ́run Baba ati Ọlọ́run Ìyá ti o jẹ́ Ẹ̀mí ati Ìyàwó.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy