Gbogbo ohun tó wà nínú Bíbélì tí a kọ ní ohun tó lé ní 1,600 ọdún ló ní ìsopọ̀ pẹ̀lú àsọtẹ́lẹ̀ àti ìmúṣẹ.
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Kírúsì Ọba àti àsọtẹ́lẹ̀ nípa Jésù tún wà nínú Bíbélì.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn ò lóye àwọn àsọtẹ́lẹ̀ inú Bíbélì nígbà tí wọ́n kọ ọ́ sílẹ̀, gbogbo wọn ló ti ní múṣẹ.
Bíbélì sọ fún wa pé a gbọ́dọ̀ sá lọ sí Síónì ká lè rí ìgbàlà nígbà tí ìjábá ńlá àti ìparun tó kẹ́yìn bá dé.
Síónì—World Mission Society Church of God, níbi tí a ti ṣe àjẹyà àwọn ajọdun Ọlọ́run, jẹ́ ibi ààbò àti igbàlà tí Ọlọ́run ti ṣèlérí fún wa.
“Kéde ní Juda, kí o sì polongo ní Jerusalẹmu, kí o sì wí pé: ‘Fun fèrè káàkiri gbogbo ilẹ̀!’ Kí o sì kígbe: ‘Kó ara jọ pọ̀! Jẹ́ kí a sálọ sí ìlú olódi.’
Fi ààmì láti sálọ sí Sioni hàn, sálọ fún ààbò láìsí ìdádúró. Nítorí èmi ó mú àjálù láti àríwá wá, àní ìparun tí ó burú jọjọ.”
Jeremiah 4:5–6
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy