Àwọn ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́ jinlẹ̀ Bíbélì tẹ̀numọ́ pé, “ ‘A’ nínú Jẹ́nẹ́sísì tọ́kasi Mẹ́talọ́kan.”
Bí ó ti wù kí ó rí, ìtẹ̀numọ́ wọn fi àìlóye wọn nípa Mẹ́talọ́kan hàn, òtítọ́ ìpìlẹ̀ ti ìsìn Kristẹni.
Wíwà ọkùnrin àti obìnrin, tí a dá ní àwòrán Ọlọ́run, jẹ́rìí pé Ọlọ́run Baba àti Ọlọ́run Ìyá wà.
World Mission Society Church of God gba gbọ́ nínú Ọlọrun Ìyá, ẹniti ó farahàn nínú ẹran ara ní àkókò yìí gẹ́gẹ́ bí àwọn aṣọ̀tẹ́lẹ̀ Bíbélì ó si fún ènìyàn ní ìyè àìnípẹ̀kun.
Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ bí àwa ti rí, . . .”
Nítorí náà, Ọlọ́run dá ènìyàn ní àwòrán ara rẹ̀, ní àwòrán Ọlọ́run ni Ó dá a, akọ àti abo ni Ó dá wọn.
Gẹnẹsisi 1:26–27
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy